Aṣiri aye wa hidden (yeah)
+
Olori aye ti fi han mi
+
O ni ki n maa ṣe jẹjẹ ma lọ
+
Oun wa lẹyin mi
+
As I don talk to the greatest one
+
I no need any kind of worry mọ
+
I go dance like David dance
+
I go sing like da di dada
+
Ọrọ mi dayọ ko dẹkun mọ
+
Ọkan mi balẹ ko lefoo mọ
+
I go do naming, I do ikomọ
+
Ki n le sọmọ lorukọ 'Tobi'
+
Ọrọ mi dayọ ko dẹkun mọ
+
Ọkan mi balẹ ko lefoo mọ
+
I go do naming, I do ikomọ
+
You heard me ọwọ Oluwa n bẹ
+
O n bẹ, o n bẹ (ye ih ye)
+
O n bẹ, o n bẹ (ye ih ye)
+
O n bẹ, o n bẹ
+
Ọwọ Oluwa n bẹ
+
O n bẹ, o n bẹ (pon the beat)
+
O n bẹ, o n bẹ (lori a')
+
O n bẹ, o n bẹ (uhn uhn uhn)
+
My life is a movie
+
Nothing dey pa, nothing dey do me
+
Ṣe b'Oluwa lo ni
+
Ṣe b'Oluwa lo ni
+
I don waka till my leg break
+
I wash face o till my eye red
+
Mo lọ fọ ori mi coz I wan mad
+
Make I no go send my soul for wrong price
+
Ọrọ mi dayọ ko dẹkun mọ
+
Ọkan mi balẹ ko lefoo mọ
+
I go do naming, do ikomọ
+
Ki n le sọmọ lorukọ 'Tobi'
+
Ọrọ mi dayọ ko dẹkun mọ
+
Ọkan mi balẹ ko lefoo mọ
+
I go do naming, do ikomọ
+
You heard me ọwọ Oluwa n bẹ
+
O n bẹ, o n bẹ (ye ih ye)
+
O n bẹ, o n bẹ (ye ih ye)
+
O n bẹ, o n bẹ
+
Ọwọ Oluwa n bẹ
+
O n bẹ, o n bẹ (pon the beat)
+
O n bẹ, o n bẹ (lori a')
+
O n bẹ, o n bẹ (uhn uhn uhn)
+


