Jah bless me o many
+
Ṣaanu mi I no fit dey beggi
+
Kọmọ 'nu mi ma pe mi ni dirty
+
Billion dollar baby o bajẹ ti
+
P'emi yatọ si wọn don't compare me
+
K'owo mi o pọ make I fear me
+
Kọmọ araye ma ṣe yẹyẹ mi
+
Tori ẹni ti o ni f'oribẹ ni
+
Death no go cut the story short
+
Ilẹ a ṣu, ilẹ a mọ if I talk
+
No more trust I do my job
+
Owo ni mo fẹ ye ye if at all
+
I know I go rise if I fall
+
Mo ra lappy ye ye ki n fi explore
+
Made a promise to my love
+
Ẹni to lọ ye ye lo ma bọ
+
Laye ta wa ka rowo na
+
Alubarika ki n ma m'oṣi o
+
Nirọ ni I rọ adaba, a rọ mi lọrun
+
Awọn malaika wọn dẹ ti fọhun
+
Laye ta wa ka rowo na
+
Alubarika ki n ma m'oṣi o
+
Nirọ ni I rọ adaba, a rọ mi lọrun
+
Awọn malaika wọn dẹ ti fọhun
+
Awọn student emi class teacher
+
I forecast mo gbe l'handicap
+
This your back gbe mi l'handicap
+
Da mi lohun give me my regard
+
Ragamofi simple laye my nigga
+
Ṣọra fayе, aye ma nika
+
Liga liga li o cash out fingers
+
Ah ah, amin o emi rirе gba
+
Laye ta wa ka rowo na
+
Alubarika ki n ma m'oṣi o
+
Nirọ ni I rọ adaba, a rọ mi lọrun
+
Awọn malaika wọn dẹ ti fọhun
+
Laye ta wa ka rowo na
+
Alubarika ki n ma m'oṣi o
+
Nirọ ni I rọ adaba, a rọ mi lọrun
+
Awọn malaika wọn dẹ ti fọhun
+



