Ìgboro demi ládé
Níbi ládé ládé
Mowá dẹnge pose lórí aiyé
Ọmọdé n pọ́nmilé
Àgbàgbà n pọ́nmilé
Mowá ti dọba nínú aiyé
Àwọn májá májá
Wọ́n fẹ́ múnmi n tipá
Wọ́n fẹ́ múnmi pátápátá
Èmi ọ̀mà kẹ̀rẹ̀ rárá
Kòsí t'ese sapá
Míò kín s'ẹran yín rárárárá
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibẹ̀ ibẹ̀ lóngbé gbé gbé
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibẹ̀ ibẹ̀ lóngbé gbé gbé
You can't stop me
I'm here to stay
You can't stop me
I'm here to stay
You can't stop me
I'm here to stay
You can't stop me
I'm here to stay
Ìgboro demi ládé
Níbi ládé ládé
Mowá dẹnge pose lórí aiyé
Ọmọdé n pọ́nmilé
Àgbàgbà n pọ́nmilé
Mowá ti dọba nínú aiyé
Àwọn májá májá
Wọ́n fẹ́ múnmi n tipá
Wọ́n fẹ́ múnmi pátápátá
Èmi ọ̀mà kẹ̀rẹ̀ rárá
Kòsí t'ese sapá
Míò kín s'ẹran yín rárárárá
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibẹ̀ ibẹ̀ lóngbé gbé gbé
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibi taní gbé gbé máàgbé
Ibẹ̀ ibẹ̀ lóngbé gbé gbé
You can't stop me
I'm here to stay
You can't stop me
I'm here to stay
You can't stop me
I'm here to stay
You can't stop me
I'm here to stay
You can't stop me
I'm here to stay
You can't stop me
I'm here to stay
You can't stop me
I'm here to stay
You can't stop me
I'm here to stay