Oba Ogo (King of Glory)
Alade alafia (Prince of Peace)
You're the God of everything
Mojuba re (I adore You)
Oga Ogo (King of Glory)
Alade Alafia (Prince of Peace)
You're perfect in all Your ways
Mojuba re (I adore You)
Hosanna
Iba Olu orun (Exalt the King of Heaven)
Halleluyah
Iba Olu orun (Exalt the King of Heaven)
Oba Ogo (King of Glory)
Alade alafia (Prince of Peace)
You're the God of everything
Mojuba re (I adore You)
Oga Ogo (King of Glory)
Alade Alafia (Prince of Peace)
You're perfect in all Your ways
Mojuba re (I adore You)
Hosanna
Iba Olu orun (Exalt the King of Heaven)
Halleluyah
Iba Olu orun (Exalt the King of Heaven)
Hosanna
Iba Olu orun (Exalt the King of Heaven)
Halleluyah
Iba Olu orun (Exalt the King of Heaven)
Iwo Labasin (We will serve you alone)
Iwo Laba bo (We will worship you alone)
Olorun Isaaki (God of Isaac)
Atoto bi aro (All sufficient God)
Aiku, Aisa, Aidibaje (He is Immortal, He is Faithful, He is Reliable)
Olorun Awon Omo Ogun (God of the divine warriors)
Ojo de Ojo fohun (The day speaks of His greatness)
Oru de Oru fi mo ogo re han (The Night speaks of His Glory)
Iro won la gbogbo awon orun ja (His presence is felt all over the heaven)
Kabiyesi o (All hail the king)
Ataye ro bi agogo (The God, capable of recrafting the world like a bell)
Ebiti oke ti n fi papa de satani mole (The mighty God, capable of holding satan captive)
Ajuba akoda (We bow to the first begotten)
Ajuba aseda (We bow to the one through whom all things are made)