Back to Top

Awé Video (MV)




Performed By: Aa!
Length: 5:14
Written by: BUKOLA ELEMIDE, COBHAMS EMMANUEL ASUQUO
[Correct Info]



Aa! - Awé Lyrics




Awe I bo lo lo ka
Ta n fi wao ka
Ibi o ba lo je a mo

Anti to n gbe le I to si
O wa o wa le yi
Ati o jo meta atabo

O wi kpe o, o
O loyun fun o
Oyun oshu meji
Oloyun fun o

Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed

Anti ton loyun fun o
O to bi e l'omo
I wo iwo na

Anti to loyun fun o
O to bi e l'omo, o bi 'mo oh oh
O bi 'mo Ire lo ni mu, ese
Irun ori,iwo dudu
Omo kpu pa ba wo lo se ri

Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed

Ewa wo ja la a fin
Oba ejigbo atabo, atako
Wan ja la fin oba La fin oba.

Wahidi omo muyina ni
Omo sekina
O foju mi ri mabo
Mabo ni le,mabo loko mabo l'eko

Mama to bi mama re
Ni mama mi, emi na bi te mi
Moo ntomo lowo f'omo loyon
Ma ko tire bami

Abo oro lan so f'omo Luabi
To ba de nu re a do n di n di
Din din
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.




Awe I bo lo lo ka
Ta n fi wao ka
Ibi o ba lo je a mo

Anti to n gbe le I to si
O wa o wa le yi
Ati o jo meta atabo

O wi kpe o, o
O loyun fun o
Oyun oshu meji
Oloyun fun o

Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed

Anti ton loyun fun o
O to bi e l'omo
I wo iwo na

Anti to loyun fun o
O to bi e l'omo, o bi 'mo oh oh
O bi 'mo Ire lo ni mu, ese
Irun ori,iwo dudu
Omo kpu pa ba wo lo se ri

Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed

Ewa wo ja la a fin
Oba ejigbo atabo, atako
Wan ja la fin oba La fin oba.

Wahidi omo muyina ni
Omo sekina
O foju mi ri mabo
Mabo ni le,mabo loko mabo l'eko

Mama to bi mama re
Ni mama mi, emi na bi te mi
Moo ntomo lowo f'omo loyon
Ma ko tire bami

Abo oro lan so f'omo Luabi
To ba de nu re a do n di n di
Din din
[ Correct these Lyrics ]
Writer: BUKOLA ELEMIDE, COBHAMS EMMANUEL ASUQUO
Copyright: Lyrics © Sony/ATV Music Publishing LLC

Back to: Aa!

Tags:
No tags yet