Back to Top

Emmanuel Adeniran featuring Ogo Ajala - Mo Wá (feat. Abiola Dosunmu) Lyrics



Emmanuel Adeniran featuring Ogo Ajala - Mo Wá (feat. Abiola Dosunmu) Lyrics




Ọmọ bàbá ni mo jẹ́
Àtúnbí nípa ẹ̀jẹ̀ ẹ rẹ̀
Mo di ẹ̀dá títún
NÍtorí ó kú fún mi
O hun àtijọ́ ti kọjá lọ
O hun titun ti dẹ́
Ẹni tí mo jẹ́ tẹ́lẹ̀ ti do o hun Ìgbàgbé
KÍyèsi mo dọmọ titun

Mo wá
Mo wá
Mo wá
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo kànkùn
Mo ní ìgbàgbọ́ pé ẹ gbó mi
Mo wá
Mo wá
Èmi ọmọ ò rẹ wá

Èmi yìí náà mo ṣákolọ
Mo dẹ̀ ṣe ìfẹ́ inú mi
Èmi yìí náà mo wùwà ìkà
Síbẹ̀sí o forí jì mí
O hun àtijọ́ ti kọjá lọ
O hun titun ti dẹ́
Èmi ọmọ tó kú, tó sì tún yè
Èmi ọmọ tó sọnù tí a sì ríi

Mo wá
Mo wá
Mo wá
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo kànkùn
Mo ní ìgbàgbọ́ pé ẹ gbó mi
Mo wá
Mo wá
Èmi ọmọ ò rẹ wá

Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Jòjòló ọmọdé kékeré jòjòló
Àwon lọ̀ré elédùmarè
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Jòjòló ọmọdé kékeré jòjòló
Àwon lọ̀ré elédùmarè
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
[ Correct these Lyrics ]

[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


Swahili

Ọmọ bàbá ni mo jẹ́
Àtúnbí nípa ẹ̀jẹ̀ ẹ rẹ̀
Mo di ẹ̀dá títún
NÍtorí ó kú fún mi
O hun àtijọ́ ti kọjá lọ
O hun titun ti dẹ́
Ẹni tí mo jẹ́ tẹ́lẹ̀ ti do o hun Ìgbàgbé
KÍyèsi mo dọmọ titun

Mo wá
Mo wá
Mo wá
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo kànkùn
Mo ní ìgbàgbọ́ pé ẹ gbó mi
Mo wá
Mo wá
Èmi ọmọ ò rẹ wá

Èmi yìí náà mo ṣákolọ
Mo dẹ̀ ṣe ìfẹ́ inú mi
Èmi yìí náà mo wùwà ìkà
Síbẹ̀sí o forí jì mí
O hun àtijọ́ ti kọjá lọ
O hun titun ti dẹ́
Èmi ọmọ tó kú, tó sì tún yè
Èmi ọmọ tó sọnù tí a sì ríi

Mo wá
Mo wá
Mo wá
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo bèèrè
Mo kànkùn
Mo ní ìgbàgbọ́ pé ẹ gbó mi
Mo wá
Mo wá
Èmi ọmọ ò rẹ wá

Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Jòjòló ọmọdé kékeré jòjòló
Àwon lọ̀ré elédùmarè
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá o
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
Jòjòló ọmọdé kékeré jòjòló
Àwon lọ̀ré elédùmarè
Ẹjẹ́ kọmọdé kó wá
Mo wá
Mo wá
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Emmanuel Adeniran, Abiola Dosunmu
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid




Emmanuel Adeniran featuring Ogo Ajala - Mo Wá (feat. Abiola Dosunmu) Video
(Show video at the top of the page)


Performed By: Emmanuel Adeniran featuring Ogo Ajala
Language: Swahili
Length: 4:59
Written by: Emmanuel Adeniran, Abiola Dosunmu
[Correct Info]
Tags:
No tags yet