[ Featuring The Asaph Crew, Salman Abraham ]
Ọba tó dámisí
(The King that keeps me)
Tó mọ mi, tó mọ̀ mí
(Who molds me and knows me)
Òun ló gbé mi ró
(He is the one that sustains me)
Sovereign God, Sovereign God
Kò s'óun tó bá mi
(Nothing happens to me)
Tọ́lọ́run ò mọ̀ sí
(Without God's Knowledge)
Gbani gbani lọ́jọ́ ìṣòro
(Deliverer in the day of trouble)
Sovereign God, Sovereign God
Nígbà tí ọ̀tá dé
(When the enemy came)
Tó dé bí ìkún omi
(Came as a flood)
Òun ló gbèjà mi
(He defends me)
Sovereign God, Sovereign God
Jésù
Olùgbàlà rere
(The good Saviour)
Olódùmarè
(God)
Sovereign God, Sovereign God