Back to Top

Remi - Aderemi omo oba Lyrics

theme

Remi - Aderemi omo oba Lyrics
Official




Ati kekere ni mo ti ba won mo pe
Gbogbo oun t'ondan ko ni wura
(Gbogbo oun t'ondan ko ni wura)
Mowo iwaju mo wo eyin oh
B'a o r'eni gbokanle shey bi a tera m'ose eni
Kaye ma se sio soro mi
Ariyo, aridunu omo ni moje
Ni k'olorun semi oh Aderemi omo oba
Many were called, few were chosen
Yet only the fittest can survive
Eyan nla eyan pataki mo fe ba won da laye
Oun rere mo fe ba won shey laye
K'ole m'ole f'ayo s'ayo
Ki'n ma r'ogun ati m'ole o lola kurisiyu oh
Mele ni kan se oh
Mele ni kan se
Bi mo se'n korin ema bami kalo
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire owo, ire ayo
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire owo, ire ayo
Ire ire
Ire ire
Gbogbo bi ole se'n anrun t'onsun falala o
Onise n sise, adura a gba tan
Won a lo n wose o (Won a lo n wose)
Bi mo se'n jeun soke
K'emi ma se jeun wale
Oke Agba mo'n gun yi o
Oke Agba mo'n gun yi o
M'o gbodo jabo o
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire owo, ire ayo
Ire ire
Ire ire
(Ire ire)
Ile aye yi o gbagidi
(Ire ire)
Dayanmo won lo j'owo lo o
(Ire ire)
Gbogbo idile Bankole ni mo ki
Victor slatt, detty go wild ire ni ti e
O ni ba won jabo laye
Babatunde semiu, tunasky autos
Egbon mori yin o
Investor BJ bami ki drizzy eleniyan
Olowo ori oko malaysia
Shobowale junior, natty 4kt, ogo bariga
Adinlewa ayomide, road manager ti o common
Abiona pelumi o pr way go Harvard
Ajilore reliance, badman bully
Gbogbo won lo ma n coordinate mi oh
Mi o ni riyin banuje o
[ Correct these Lyrics ]

We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


We currently do not have these lyrics. If you would like to submit them, please use the form below.


English

Ati kekere ni mo ti ba won mo pe
Gbogbo oun t'ondan ko ni wura
(Gbogbo oun t'ondan ko ni wura)
Mowo iwaju mo wo eyin oh
B'a o r'eni gbokanle shey bi a tera m'ose eni
Kaye ma se sio soro mi
Ariyo, aridunu omo ni moje
Ni k'olorun semi oh Aderemi omo oba
Many were called, few were chosen
Yet only the fittest can survive
Eyan nla eyan pataki mo fe ba won da laye
Oun rere mo fe ba won shey laye
K'ole m'ole f'ayo s'ayo
Ki'n ma r'ogun ati m'ole o lola kurisiyu oh
Mele ni kan se oh
Mele ni kan se
Bi mo se'n korin ema bami kalo
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire owo, ire ayo
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire owo, ire ayo
Ire ire
Ire ire
Gbogbo bi ole se'n anrun t'onsun falala o
Onise n sise, adura a gba tan
Won a lo n wose o (Won a lo n wose)
Bi mo se'n jeun soke
K'emi ma se jeun wale
Oke Agba mo'n gun yi o
Oke Agba mo'n gun yi o
M'o gbodo jabo o
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire ire
Ire owo, ire ayo
Ire ire
Ire ire
(Ire ire)
Ile aye yi o gbagidi
(Ire ire)
Dayanmo won lo j'owo lo o
(Ire ire)
Gbogbo idile Bankole ni mo ki
Victor slatt, detty go wild ire ni ti e
O ni ba won jabo laye
Babatunde semiu, tunasky autos
Egbon mori yin o
Investor BJ bami ki drizzy eleniyan
Olowo ori oko malaysia
Shobowale junior, natty 4kt, ogo bariga
Adinlewa ayomide, road manager ti o common
Abiona pelumi o pr way go Harvard
Ajilore reliance, badman bully
Gbogbo won lo ma n coordinate mi oh
Mi o ni riyin banuje o
[ Correct these Lyrics ]
Writer: Bankole Aderemi
Copyright: Lyrics © O/B/O DistroKid
LyricFind

Back to: Remi



Remi Aderemi omo oba Video


Performed By: Remi
Language: English
Length: 3:07
Written by: Bankole Aderemi

Tags:
No tags yet